HYMN 274

(FE 296)
“Anu ni emi nfe" - Matt. 9:13



1.  B’ERU ese re ba nwo o Iorun 

     Pe Jesu wole Okan re

     B'o ndaniyan isoji Okan re 

     Pe Jesu wole okan re.

Egbe:  Le'yemeji re sonu 

           Ba Oluwa re laja

           Si okan re paya fun 

           Pe Jesu wole okan re.


2.  Bi o ba nwa iwenumo kiri 

     Pe Jesu wole okan re

     Oni ‘wenumo ko jina si o 

     Pe Jesu wole okan re.

Egbe:  Le'yemeji re sonu...


3.  B'lgbi wahala ba ngba o kiri 

     Pe Jesu wole okun re

     B‘afo ba wa ti aiye ko le di 

     Pe jesu wole okan re. 

Egbe:  Le'yemeji re sonu...


4.  Bi ore t‘o gbekele ba da o 

     Fe Jesu wole okan re

     On nikan ni Olubanidaro 

     Pe Jesu wole okan re.

Egbe:  Le'yemeji re sonu...


5.  B’o nfe korin awon alabukun 

     Pe Jesu wole okan re

     Bi o nfe wo agbala isimi 

     Pe Jesu wole okan re.

Egbe:  Le'yemeji re sonu 

           Ba Oluwa re laja

           Si okan re paya fun 

           Pe Jesu wole okan re.  Amin

English »

Update Hymn