HYMN 273
C.M.S. 171 H.C 149 C.M (FE 293)
“Ongbe Olurun ngbe okan" - Ps. 42:2
1. BI agborin ti nmi hele
S'ipa Odo omi
Beni okan mi nmi si O
Iwo Olorun mi.
2. Orungbe Re ngbe Okan mi
Olorun alaye;
Nigbawo ni ngo r'Oju Re,
Olorun Olanla?
3. Okan mi o se rewesi
Gbekele Olorun
Eniti y'o so ekun re
D’orin ayo fun o.
4. Y’o ti pe to, Olorun mi,
Ti ngo d'eni gbagbe?
T’ao ma ti mi sihin, sohun
B‘eni ko ni ‘bugbe.
5. Okan mi o so rewesi?
Gbagbo ‘wo o si ko
Orin iyin s’Olorun re
Orisun emi re. Amin
English »Update Hymn