CMS 170 t.H.C. 167 S.M (FE 292) "Ese ti enyin fi se ojo be, enyin onigbagbo kekere?" - Matt 8:26 1. SA dake okan mi Oluwa re wa mbe Enit' o ti se ileri Yio fe mu u se. 2. On ti fa O lowo Omu o de ‘hin yi Y‘o pa o mo la ewu ja Tit‘ opin aiye re. 3. Nigbat‘iwo ti bo Sinu wahala ri lgbe re na ki On ha gbo T‘o si yo O kuro? 4. B’ona ko tile dan Yio mu o de ‘le Sa ti wahala aiye tan O san fun gbogbo re. Amin