C.M 1. JE k‘a yin Oluwa isimi Pelu awon Mimo Ti nf'ayo at'orin didun Lo s‘simi ailopin. 2. Oluwa, b'a ti nranti Re N'ibukun wa npo si Nipa orin iyin l'a nko B‘a ti y'ayo ‘segun. 3. Lojo ayo yi l‘Olorun Oro ayeraye F‘ise nla han, t'o logo ju Ti iseda aye. 4. O jinde, eni f’irora Ra gbogb’ eda pada Ise nla ni dida aye Idande ju yi lo. Amin