C.M (FE 287) "Oju Oluwa mbe nibi gbogbo" - Owe 15:3 1. ISE gbogbo ti awa nse Ni Olorun ti ri Ero gbogbo t'o wa ninu Ni Olorun si mo. 2. A ko le f‘ese wa pamo Gbogbo won l'O ti mo A npuro, a ntan ‘ra wa je B’a ro pe ko mo won. 3. Ohun gbogbo han ni gbangba Ni oju Olorun Okunkun ati imole Si ri bakanna fun. 4. Olorun, je k'a ranti pe Oju re si ri wa Si jeki awa k’o beru Lati dese si O. Amin