S.124 t.H.C 336 11s (FE 286) "Ikilo meta - Ma ba ja, ma bi ninu ma pa ina Emi" - 1 Tess. 5:19 1. lWO elese, Emi nfi anu pe Okan re t‘o ti yigbi ninu ese Ma se ba Emi ja, ma pe titi mo Ebe Olorun re Ie pari loni. 2. Omo Ijoba, mas'eru ese mo; Gb’ebun Emi Mimo ati itunu Ma bi Emi ninu, Oluko re ni K’a ba le se Olugbala re logo. 3. Tempili d'ibaje ewa re d‘ile lna pepe Olorun fere ku tan Bi a fi ife da, O si le tun ran Mase pa ‘na Emi, Oluwa mbo wa. Amin