HYMN 255

C.M.S 163 .t.H.C 152 CM (FE 275)
“Olorun, sanu fun mi elese" - Luku 18:13




1.  OLU WA, b’agbowode ni 

     Mo gb’okan mi le O 

     Oluwa, f' ore-ofe wi

     K‘o se anu fun mi.


2.  Mo lu aiduro aiya mi 

     Ekun at’irora

     K‘o gb'okan mi’nu irora 

     K’o se anu fun mi.


3.  N'itiju, mo jew’ ese mi 

     Jo fun mi ni ireti

     Mo be, ‘tori eje Jesu 

     K’o se anu fun mi.


4.  Olori elese ni mi 

     Ese mi p‘apoju 

     Nitori iku Jesu wa 

     K’O se anu fun mi.


5.  Mo duro ti agbelebu 

     Nko sa f’ojiji re

     Ti Olorun to po l’anu

     O ti sanu fun mi.  Amin

English »

Update Hymn