Tune: C.M.S 161 K. 523. t. H. C. 17 L.M (FE 274) "Abo mi mbe lodo Olorun” - Ps. 7:10 1. PELU mi nibiti mo nlo Ko mi l’ohun t’emi o se Sa gbo aro at’oro mi K‘o f'ese mi le ona Re. 2. Fi opo ife Re fun mi Ma se alabo mi lailai Fi edidi Re s’aiya mi Je ki Emi Re pelu mi. 3. Ko mi bi a ti gbadura Jeki emi gba Iwo gbo Ki nkorira nkan t’ O ko fe K’emi si fe ‘hun ti O fe. Amin