HYMN 252
C.M.S 159, t.H.C 156 L.M (FE 272)
“OIuwa, kiyesi aroye mi" - Psalmu 5:1
1. OLUWA, gbo aroye mi
Gbo adura ikoko mi
Lodo Re nikan Oba mi
L’emi O ma wa iranwo.
2. L’oro Iwo o gbohun mi
L’afemojumo ojo na
Ni odo Re l’emi o wo
Si O l’emi o gbadura.
3. Sugbon nigb’ore-ofe Re
Ba mu mi de agbala Re
Odo Re I'em’o teju mo
Nibe, ngo sin O ni rele.
4. Je k’awon t’o gbekele O,
L’ohun rara wi ayo won
Jek’ awon t’lwo pamo yo
Awon t’o fe oruko Re.
5. Si Olododo l’Oluwa
O na owo ibukun Re
Oju rere Re l’enia Re
Yio si fi se asa won. Amin
English »Update Hymn