C.M.S 155 H.C 148 S.M (FE 270) "Ranti Oluwa" - Ps. 106: 4 1. JESU, jo ranti mi K'O si w'ese mi nu Gba mi low‘ese 'binibi Si we okan mi mo. 2. Jesu, jo ranti mi Em' eni nilara Ki mse ‘ranse t'o n‘ife Re Ki m'to ‘simi Re wo. 3. Jesu, jo ranti mi Muse je ki nsako N’nu damu on okun aiye F'ona orun han mi. 4. Jesu, jo ranti mi, Gba gbogbo re koja Ki nle r’ogo ainipekun Ki nsi le ba O yo. 5. Jesu, jo ranti mi Ki nle korin loke Si baba, Emi ati Re Orin ‘yin at' ife. Amin