HYMN 249

C.M.S.154 H.C 323, C.M (FE 269)
“Awa ko ni Olori Alufa ti o se
alaimo edun ailera wa" - Heb. 4:15



1.  A F‘AYO ri ore-ofe 

     T'Alufa giga wa,

     Okan Re kun fun iyonu 

     lnu Re nyo fun ‘fe.


2.  Tinutinu l'o ndaro we 

     O mo ailera wa

     O mo bi idanwo ti ri 

     Nitori O ti ri.


3.  On paapo l‘ojo aiye Re 

     O sokun kikoro

     O mba olukuluku pin 

     Ninu iya ti nje.


4.  Je ki a f’igbagbo ‘rele 

     W’anu at’ipa Re

     Awa o si ri igbala 

     L'akoko iyonu.  Amin

English »

Update Hymn