C.M.S. 151 t.H.C 133. C.M (FE 268) "Omokunrin tujuka, a dari ese re ji o" - Matt 9:2 1. JESU mi, mu mi gb'ohun Re S'oro alafia; Ghogbo ipa mi y'o dalu Lari yin Ore Re. 2. Fi iyonu pe mi l'omo K’ o si dariji mi; Ohun na yio dunmo mi B‘iro orin orun. 3. Ibikibi t'o to mi si, L’emi o f' ayo lo Tayotayo l’emi o si Dapo m'awon oku. 4. Gba eru ebi ba koja Eru mi ko si mo Owo t’o fun 'dariji ka, Y'o pin ade iye. Amin