HYMN 244

CM.S 144 H.C 147 C.M (FE 264) 
"E je ki a fi igboiya wa si ibi ite 
ore-ofe:" - Heb. 4:16



1.  OKAN mi sunmo ‘te anu 

     Nibi Jesu ngb’ebe 

     F’irele wole l’ese Re, 

     'Wo ko le gbe nibe.


2.  Ileri Re ni ebe mi

     Eyi ni mo mu wa

     lwo npe okan t’eru npa 

     Bi emi Oluwa.


3.  Eru ese wo mi l'orun 

     Ese use mi n‘ise 

     Ogun I'ode, eru ninu 

     Mo wa isimi mi.


4.  Se Apata at' Asa mi 

     Ki nfi O se abo

     Ki ndoju ti Olufisun 

     Ki nso pe Kristi ku.


5.  Ife Iyanu! Iwo ku

     Iwo ru itiju

     Ki elese b‘iru emi 

     Le be I'oruko Re.  Amin

English »

Update Hymn