HYMN 242

(FE 262)
C.M.S. 142 T. t. H.C 246 SM 
"Jesu sokun” - John 11:35



1.  KRISTI sun f‘elese 

     Oju wa o gbe bi? 

     K‘omi ronu at‘ikanu 

     Tu jade l'oju wa.


2.  Omo Olorun nsun 

     Angeli siju wo!

     K‘o damu, iwo okan mi 

     O d’omi ni fun o.


3.  O sun k’awa k‘o sun

     Ese bere ekun

     Orun nikan ni ko s’ese 

     Nibe ni ko s'ekun.  Amin

English »

Update Hymn