C.M.S 492, t.H.C 368, 6s 5s (FE41) “Fi eti si mi Oluso aguntan Israeli” - Ps. 80:1 1. OLUS’ AGUTAN mi, Ma bo mi titi, Olus’agutan mi, Ma to ese mi. 2. Di mi mu, si to mi, Ni ona hiha B’O ba wa lodo mi, Emi ko sina. 3. Sin mi s’ona orun Ni ojojumo Ma busi ‘gbagbo mi Si mu mi fe O. 4. K'ayo at'alafia Ti odo Re wa K'iye ainipekun Le je ayo mi. 5. Ma pese okan mi, Ni ojojumo Si je k‘Angeli Re, Sin mi lo ile. Amin