HYMN 238
C.M.S.152 t.H.C. 27
tabi A. &. M 101 S.M (FE 258)
"Emi korira ara mi, mo si ronupiwada
se toto ati ninu ekura ati eru" - Jobu 42:6
1. ALAIMO ni emi
Olorun Oluwa!
Emi ha gbodo sunmo O,
T'emi t'eru ese?
2. Eru ese yi npa
Okan buburu mi
Yio ha si ti buru to
L'oju Re mimo ni!
3. Emi o ha si ku
Ni alainireti?
Mo r'ayo ninu iku Re
Fun otosi b‘emi.
4. Eje ni ti o ta
T’ise or‘ofe Re
Le w'elese, t'o buru ju
Le m‘okan lile ro.
5. Mo wole l'ese Re
Jo k‘ O dariji mi
Nihin l’emi o wa titi
Wo o wipe "Dide." Amin
English »Update Hymn