HYMN 234

K. 194 t.H.C 156 DIM (FE 254)
"O si pe oruko re ni Ebeneseri wipe: titi de
ihin li Oluwa ran wa Iowa” - 1 Sam. 7:12



1.  OLUWA ati ’gbala wa 

     Amona at’agbara wa 

     L'o ko wa jo l'ale oni

     Jek’ a gbe Ebeneseri ro 

     Odun t’a ti le koja

     Ni On f’ore Re de lade 

     Otun l’anu Re l’Owuro 

     Nje ki ope wa ma po si!


2.  Jesus t’o joko lor' ite

     L’a fi Halleluyah wa fun 

     Nitori e nikansoso

     L'a da wa si lati korin

     Ran wa lowo lati kanu 

     Ese odun t’o ti koja

     Fun ni k‘a lo eyi ti mbo

     S'iyin Re ju odun t’o lo.  Amin

English »

Update Hymn