HYMN 225

C.M.S 97 t.H.C 43 D. 7s. (FE 224)
"Kili emio nyin?” - Jak. 4:14 



1.  ODUN miran ti koja

     Wawa l’akoko na lo 

     Nini eyit'a wa yi

     Yio s'arimo opo

     Anu l’o fi da wa si

     A ha lo anu na bi?

     K’a bi ‘ra wa ba se tan? 

     B'a o pe wa l’odun yi.


2.  Aiye bi ibi ija 

     Egbegberun l'o nsubu 

     Ofa iku t’o si nfo

     A le ran s’emi b'iwo 

     Nigb’ a nwasu t’a si ngbo 

     Oluwa, jek’a saro 

     P'aiyeraiye sunmole

     A nduro l’eti bebe.


3.  B’a gba wa lowo ese

     Nipa ore-ofe Re

     Nje ‘ma bo’ n' ipe o je

     K'a le lo, k'a r’oju Re 

     F'enia Re l’aiye yi

     K’anu wa l'odun titun

     Odun t'o l’ayo ju yi 

     L'eyi t’o mu won de ‘le.  Amin

English »

Update Hymn