C.M.S 96 C.M (FE 241) "Je ki ise Re ki o han si awon omo odo Re" - Ps. 90:16 1. OLORUN at' ireti mi Oro Re l‘onje mi Owo Re gbe mi ro l’ewe Ati l’odomode. 2. Sibe mo rohun iyanu ‘O nse ni ododun Mo fi ojo mi ti o ku S’iso Tire nikan. 3. Ma ko mi, nigba‘agbara ye Ti ewu ba bo mi Ki ogo Re ran yi mi ka Nigbati mo ba ku. Amin