C.M.S 489, H.C 489, S.M (FE 39) “E sunmo Olorun...On yio si sunmo nyin” - Jak. 4:8 1. JESU, a w’odo Re L’Ojo Re mimo yi, To wa bi awa ti pejo Si ko wa fun ‘ra Re. 2. Dari ese ji wa, Fun wa l’Emi Mimo Ko wa k’ihin je ibere Aiye ti ko l’opin. 3. F'ife kun aiya wa, Gba ‘se oluko wa; K‘awa at' awon le pade Niwaju Re l'oke. Amin