HYMN 213
H.C. 103. t.H.C. 149 C.M.
C.M.S. 98 (FE 232)
"Igba mi mbe Ii owo Re" - Ps. 31:15
1. IGBA mi mbe li owo Re;
A fe ko wa nibe;
A f’ara wa at'ore wa,
Si abe iso Re.
2. Igba mi mbe li owo Re,
Awa o se beru?
Baba kio je k‘ omo Re,
Sokun li ainidi.
3. Igba mi mbe li owo Re,
‘Wo I' ao gbekele;
Tit’ ao f‘aiye osi sile;
T’ a o si r' ogo Re.
4. Igba mi mbe li owo Re;
Jesu t’agbelebu
Owo na t‘ ese mi dalu;
Wa di alabo mi.
5. Igba mi mbe li owo Re;
Ngo ma simi le O,
Lehin ‘ku l‘ow’ otun Re;
L’emi o wa titi lai. Amin
English »Update Hymn