HYMN 205
1. TAN ihin na kale, jakejado aiye
K'awon ti eru npa
Mo pe igbala de
K‘awon t’ise ti Krist’
So ihin ayo na.
Egbe: Olutunu ti de, Olutunu ti de
Emi Iat’ oke wa, ileri
Baba wa
Tan ihin na kale, jakejado aiye
Olutunu ti de.
2. Oba awon oba, wa f 'iwosan fun wa
O wa ja ide wa, O mu igbala wa
K‘olukuluku wa, korin isegun pe.
Egbe: Olutunu ti de...
3. lfe iyanu nla, a! mba rohin na
Fun gbogbo enia, ehun or‘ofe Re
Emi omo egbe, di omo igbala.
Egbe: Olutunu ti de...
4. Gbe orin ‘yin soke
s'olurapada wa
K‘awon mimo l‘oke
Jumo ba wa gberin
Yin ife re titi, ife ti ko le ku.
Egbe: Olutunu ti de, Olutunu ti de
Emi Iat’ oke wa, ileri
Baba wa
Tan ihin na kale, jakejado aiye
Olutunu ti de. Amin
English »Update Hymn