S M S M (FE 216) 1. OJO nla kan ma mbo T'Olusiro y'o de, Gbogbo eniyan y'o ri Aye yio wariri. 2. Igbagbo re ha da Wo ti ko m'Olorun T'o f'eda se igbekele T'o f' Oluwa sile. 3. Ayo pupo yio wa, L'okan ti Jesu ngbe Ti nwon ti ko aiye sile T'o gba Emi Mimo. 4. E ku 'se Oluwa Enyin ara at'ore Ki Baba Olodumare Bukun fun gbogbo wa. Amin