C.M.S 59 H.C 109 8s. 7s (FE 212) “Ife gbogbo orile yio si de” - Hag. 2:7 1. WA, Iwo Jesu t’a nreti T‘a bi lati da ni n'de Gba wa low’ eru at‘ese Jek’ ari isimi re. 2. lwo ni itunu Israel Ireti Onigbagbo Ife gbogbo orile ede Ayo okan ti nwona. 3. Wo t'a bi lati gba wa la, Omo ti a bi l’Oba Ti a bi lati joba lai, Jeki ijoba re de. 4. Fi Emi Mimo Re nikan Se akoso aiya wa Nipa itoye, kikun Re Gbe wa s’ori ite Re. Amin