C.M.S 65 t. H.C 14 L.M (FE 211) "Awa mo pe Omo Olorun de" - I John 5:20 1. ONIDAJO na de, O de! Beni ‘pe keje ti ndun nwi Manamana nko, ara nsan Onigbagbo y’o ti yo to! 2. A ngbo, Angel orun nwipe Jesu Oluwa wa d‘ade Ore’Ofe l’On fi damure Ogo l‘On fi s'oso boju. 3. ‘Wo sokale l’or‘ite Re O gba ijoba fun ‘ra Re Ijoba gbogbo gba Tire Nwon gba b’Oluwa t’o segun. 4. Gbogbo ara orun, e ho At’ enia Oluwa wa, Oga ogo t’o gba ola Yio joba lai ati lai. Amin