HYMN 190

C.M.S 51 H.C 72 t.s 219 
L.M - Ps. 102:20



1.  OJO ‘binu ojo eru 

     T’aiye at’orun y‘o fo lo 

     Kin'igbekele elese

     Y‘o se le yoju l'ojo na?


2.  Nigbati orun y‘o kako 

     Bi awo ti a fi ina sun 

     T‘ipe ajinde y‘o ma dun 

     Kikankina, teruteru.


3.  A! l'ojo na, ojo ‘binu

     T eda yio ji si dajo 

     Kristi, jo ji si dajo

     ‘Gba t’ayie t'orun ba fo lo.  Amin

English »

Update Hymn