HYMN 187
C.M.S 48 H.C 64 C.M (FE 205)
"O ti bojuwo, O si ti da awon enia
Re ni ide" - Luke 1:68
1. GBO 'gbe ayo! Oluwa de,
Jesu t'a seleri
Ki gbogbo okan mura de
K'ohun mura korin.
2. O de lati t'onde sile
L'oko eru esu
Lekun 'de fo niwaju Re
Sekeseke rin da.
3. O de larin 'baje aiye
Lati tan 'mole Re
Lati mu k'awon afoju
Le f'oju won riran.
4. O de 'tanu f'okan 'rora
Iwosan f'agbogbe
Pelu 'sura or-ofe Re
Fun awon talaka.
5. Hosanna, Ob'Alafia
A o kede bibo Re;
Gbogbo orun y'o ma korin
oruko t'a feran. Amin
English »Update Hymn