CM.S 50 O. t H. C. 141 7s (FE 201) "Idajo nla" - Juda 6 1. OJO 'dajo on 'binu Ojo ti Jesu pa ni Gbobgo a so n'jo na! 2. Kikan n'ipe o ma dun Isa oku yio si, Gbogbo oku y'o dide. 3. Iku papa y'o diji Eda gbogbo y'o dide Lati jipe Olorun. 4. A o si Iwe sile A o si ka ninu re Fun 'dajo t'o ku t'aye. 5. Onidajo Ododo Jo w'ese mi gbogbo nu K'ojo siro na to de. Amin