HYMN 171
H.C 59 6. 8s (FE 189)
“Nwan nyo niwaju Re gege bi
ayo ikore" - Ise 9:13
1. OLUWA ‘kore, ‘Wole l'a nyin
lleri Re ‘gbani ko ye
Orisi igba si nyipo,
Ododun kun fun ore Re
Lojo oni, awa dupe
Jek‘ iyin gba okan wa kan.
2. B'akoko ‘rugbin mu wa yo
B'igba erun nmu oru wa;
‘Gbati owo ojo ba nrinle
Tab'igbat’ikore ba pon
'Wo Oba wa l'a o ma yin
'Wo l‘alakoso gbogbo won.
3. Ju gbogbo re lo, nigbati
Owo Re fun opo ka ‘le
Gba t'ohun ayo, gbilekun
B'eda ti n ko ire won jo;
Awa pelu y’o ma yin O
Ore Re ni gbogbo wa npin.
4. Oluwa ‘kore, Tire ni,
Ojo ti nro orun ti nran
lrugbin ti a gbin sile
Tire l’ohun ti nmu dagba:
Otun l’ebun Re l’ododun
Otun n’iyin Re l’enu wa. Amin
English »Update Hymn