HYMN 164

O.t. H.C 264 D8s. 7s (FE 183)
"Gbogbo nwon si kun fun Emi
Mimo"- Ise 2:4



1.  BABA wa orun, awa de, 

     Awa alailagbara

     Fi Emi Mimo Re kun wa, 

     K’o so gbogbo wa d’otun 

     Wa! Emi Mimo, jare wa! 

     F'ede titun s’okan wa 

     Ebun nla Re ni la ntoro 

     T'ojo nla Pentikosti.


2.  Ranti ileri Re, Jesu

     Tu Emi Re s'ara wa,

     Fi alafia Re fun wa, 

     T'aye ko Ie fifun ni

     Wa! Emi Mimo, jare wa! 

     Pa ese run l'okan wa, 

     Ebun nla Re ni l'a ntoro 

     T'ojo nla Pentikosti.


3.  Adaba orun! ba le wa,

     Fi agbara Re fun wa;

     Ki gbogbo orile ede

     Teriba f’Olugbala,

     K‘a gburo Re jakejado

     ILe okunkun wa yi 

     Ebun nla Re ni l'a ntoro 

     T’ojo nla Pentikosti.  Amin

English »

Update Hymn