HYMN 161

L.M. (FE 180)



1.  EMI Orun wa nisisyi

     Mi si wa b‘a ti ngbadura 

     Orisun ‘ye titun ni O,

     Imole ojo wa titun.


2.  O mba wa gbe l‘ona ara, 

     lwo ko si jinna si wa

     A o gbo ohun Re Nitosi 

     Emi Re mb'emi wa soro


3.  Krist’ l'Alagbawi wa loke 

     Iwo l’Alagbawi n‘nu wa 

     Fi otito da wa lebi 

     Gbogbo awawi ese wa.


4.  Okan mi se aigbagbo po! 

     Mo m’ona at’Oluto mi; 

     Dariji mi, Wo Ore mi 

     Fun ‘yapa mi igbukugba.


5.  Pelu mi n‘ igba ko s’ore

     Ti mo le f’asiri mi han 

     ‘Gbat'eru Ieke l‘okan mi, 

     Jeki nmo O l’Olutunu.  Amin

English »

Update Hymn