HYMN 160
O.t. H.C 247, D.S.M (FE 179)
“Nwon si kun fun Emi Mimo" - Ise 2:4
1. EMI Olorun mi,
L‘ojo ‘tewogba yi
Gege b’ojo Pentikosti
Sokale l’agbara
Lokan kan l‘apade
Ninu ile Re yi
A duro de ileri Re,
A duro de Emi.
2. B’iro iji lile,
Wa kun ‘nu ile yi
Mi Oni isokan si wa
Okan kan, imo kan,
Fun ewe at‘agba
L‘ogbon at’oke wa
Fi okan gbigbona fun wa
K'a yin, k’agbadura.
3. Emi imole wa,
Le okunkun jade
Siwaju ni k’imole tan
Tit’ d’osangangan
Emi otito wa,
S’amona wa titi
Emi Isodomo, si wa
S’okan wa di mimo. Amin
English »Update Hymn