CM.147, t.H.C 400 C.M. (FE 170) "Woli nIa dide li arin wa” - Luku 7:16 1. 'WO, owon Olurapada A fe ma gburo Re Ko s'orin bi oruko Re, T'o le dun t'abo re. 2. A! a ba le ma gbohun Re, L’anu soro si wa, Nin’ Alufa wa l’a o yo Melkisedek giga. 3. Jesu ni y’o se orin wa, Nigbat’ a wa l‘aiye A o korin ife Jesu 'Gba nkan gbogbo baje 4. Nigba 'ba yo soke lohun Pelu 'jo, eni Re 'Gbana a o korin kikan Kristi'mi y'o j'orin wa. Amin