HYMN 150

ORIN lYlN (FE 168)



1.  OHUN t’Oluwa yio se

     Oba mi ko fi y’enikan. x4

Chorus:  Awon enia pataki lo ti ku

              Opo enia pataki lo ti Io o

              Eda to ba wa laye, x4

              Ko wa fi iyin f'onise Nla. x3


2.  Ore t‘Oluwa ba se 

     Ara mi jowo fi han o. x4 

Chorus:  Awon enia pataki...


3.  Ore t'Oluwa ba se 

     Ore mi jowo fi han o. x4 

Chorus:  Awon enia pataki...


4.  Omo l'Olorun fun o

     Ore mi jowo fi han o. x4 

Chorus:  Awon enia pataki...


5.  lke l’Olorun fun o 

     Ore mi jowo fi han o. x4

Chorus:  Awon enia pataki...


6.  Ohun t’Oluwa fun o

     Jowo fi yin Messiah o. x4

Chorus:  Awon enia pataki lo ti ku

              Opo enia pataki lo ti Io o

              Eda to ba wa laye, x4

              Ko wa fi iyin f'onise Nla 

              Ko wa fi iyin f'onise Nla

              Ko wa fi iyin f'onise Nla.  Amin

English »

Update Hymn