(FE 153) Tune: F’eru re f’a fefe S.M. 1. F'IBUKUN f’Oluwa! K’okan at’inu mi, Pel'ahon mi yin Oko Re, Fun gbogbo ore Re. 2. F’ibukun f’Oluwa Okan mi ma gbagbe Lati s’ope, Iati f'iyin Fun opo anu Re. 3. O f'ese re ji O O mu ‘rora re lo O wo gbogbo arun re san, O so o d’atunbi. 4. O f' onje f ‘alaini lsimi f’ojiya; Y'o se ‘dajo agberaga Y’o gbeja alaise. 5. O f‘ise 'yanu Re, Han, lat’ owo Mose Sugbon oto at’ore Re L'o fi ran Omo Re. Amin