Tune: CM 1. A k’orin s’Omo Olorun Odagutan t’a pa Ti orun ati aye mbo T'O ye lati joba. 2. Si O l’awon Angeli nke L'ekun gbogbo orun Mimo mimo, mim'Olorun T'ogo at’om'ogun. 3. ljo Re li aye dapo Lati ma kepe O Didan Olanlan Olorun T'O l‘agbara gbogbo. 4. Larin won ni gbogbo wa nfe Lai yin eje re Joba l’aye ati l'orun Wo Omo Olorun. Amin