HYMN 130

C.M.S. 565, H.C 587 t.H.C. 581 
8s. 7s (FE 147)
"Mo gbonhun nla kan ti opolopo enia
l'orun wipe, Alleluyah" - Ifihan 19:1



1.  ALLELUYAH! orin t’o dun 

     Ohun ayo ti ki ku 

     Alleluyah! orin didun 

     T‘awon t‘o wa l’orun fe 

     N'ile ti Olorun mi ngbe

     Ni nwon nko tosan-toru.


2.  Alleluyah! ljo orun

     E le korin ayo na, 

     Alleluyah! orin ‘segun 

     Ye awon t'a rapada 

     Awa ero at‘alejo

     Iyin wa ko nilari.


3.  Alleluya! orin ayo

     Lo ye wa nigbagbogbo 

     Alleluya! ohun aro

     Da mo orin ayo wa; 

     Gbat' a wa laiye osi yi, 

     A ngbawe f‘ese wa.


4.  Iyin dapo m‘adua wa; 

     Gbo tiwa, Metalokan! 

     Mu wa de 'waju Re I‘ayo 

     K'a r‘Odagutan t‘a pa

     K‘a le ma ko Alleluyah, 

     Nibe lai ati lailai.  Amin

English »

Update Hymn