P.B 408 4s (FE 146) 1. YIN Olorun Abraham To gunwa lok’orun Eni agba aiyeraiye Olorun ‘fe Emi Jehofa nla T'aiye t‘orun njewo Mo yin oruko mimo Re Olubukun. 2. B'ipa ara baje T’aiye t’esu ndena Ngo dojuko ile Kenaan, Nip'ase Re. Ngo la ibu koja Ngo tejumo Jesu Larin aginju to leru Ngo ma rin lo. 3. S'Olorun Oba l‘oke L'olor‘ Angeli nke Wipe Mimo Mimo Olodumare, Eniti o ti wa, Ti yio si wa lailai, Emi Jehovah Baba nla Kabiyesi. Amin