(FE 142) Tune: Mase sise lo L.M 1. GBOGBO eda abe orun E f’iyin fun Eleda wa, Ki gbogbo orile-ede Korin iyin Olugbala. 2. Oluwa, anu Re ki ti, Oto Re si duro lailai Iyin Re y’o tan kakiri Tit'orun y’o la laiwo mo. Amin