HYMN 124

C.M.S 554, H.C 54, L.M (FE 141)
"E ho iho ayo si Oluwa, enyin ile
gbogbo - Ps. 100:1



1.  NIWAJU ite, Jehovah,

     E f'ayo sin, oril’ede

     Mo p’Oluwa, on kanso ni 

     O le da, O si le parun.


2.  lpa Re, laisi ‘ranwo wa, 

     L‘o f’amo da wa l’enia 

     Nigbat' a sako b’agutan 

     O tun mu wa si agbo Re.


3.  A o f‘orin sunmo ‘le Re; 

     Lohun giga l'a o korin 

     Aiye l'oniruru ede

     Y’o f'iyin kun agbala Re.


4.  Ase Re gboro b’agbaiye 

     Ife Re pe b’ayeraye

     Oto Re yio duro lailai 

     Gbat’ odun ki yio yipo mo.  Amin

English »

Update Hymn