8.8.8.5 1. YIN Oluwa, enyin mimo Awa ti je ni ‘gbese to? Je k'a mu gbogbo ini wa Wa pelu ayo. 2. Jesus l'Oko t'o dara ju O nfun wa l'okun l'oju ‘ja lbi kan ko le de ba wa ‘Gbat‘ a gbekele. 3. Gbekele yin le, eyin mimo Olododo l’Olorun wa Ko s'ohun to le, ya awon T‘O fe l‘odo Re. 4. F'ore ofe Re pa wa mo K‘a le tubo faramo O Titi ao fi de ‘nu ogo At‘ ayo l‘orun. 5. ‘Gbana l‘ ao de ibi mimo ‘Gbana l'a o si di mimo Ayo nla ti a ko so Ni y‘o je ti wa. Amin