HYMN 102

8.8.8.8.8.8.6.6.6.6



1.  E YO loni pe l‘ohun kan

     E korin igbega soke

     E yo, eyin Oluwa wa

     T'apa Re mu igbala wa

     lse Ife npokiki

     Titobi oruko Re

     Olorun kan laelae

     To ti f'anu Re han

     K'eniyan mimo Re juba Re.


2.  Gba banuje de, a kepe

     O si gbo gbogbo ‘aroye wa

     Gbekele boti wu kori

     Agbeniro ni ife Re

     Orin iyin ‘segun

     Lokan wa y’o ko si

     Gbogb’ohun y'o ko pe

     ‘E yin Olorun wa

     K’eniyan mimo re juba Re.


3.  E yo, loni pe l’ohun kan

     E korin igbega soke

     E yo, eyin Oluwa wa

     T’apa Re mu igbala wa

     Ise Ife npokiki

     Totibi oruko Re

     Olorun kan laelae

     To ti f‘anu Re han

     K'eniyan mimo Re juba re.  Amin
 

English »

Update Hymn